Happy NeW Month FashMaverickBlog Readers/ Visitors!!!

Wishing all FBR/Blog visitors a happy new month, I pray y'all that have seen the first of DECEMBER, shall all see it last day and the coming years, do have a splendid, blissful, fruitful, spontaneous, prosperous, full of blessing, mercy, favour MONTH and also do not forget to always Thank God @ all times:

You could call on him through any of Gods's Name:
Oba Akikitan Apa-nla-to sole-aye-ro; Adeda; Aseda; Ameda; Alagbada-ina; Alawotele-oorun; Gbengbeleku to ndara nibi to gbe wun; Alaani; Agbani; Afuuni; Atoni; Alewilese; Aleselewi; Gbani-gbani ti-aye-nsaaya; Ariro-ala; Arabaribiti; Aribirabata; Sonso ori abere to soro fun satani lati joko le; Opabi-da-sobi-dire; O joko kiribiti kale lajule orun, Oba mi to tele aye bi eni teni; O ta sanmo bi eni taso; Alapa kabikabi ti nkabi danu lori awon omo; Akobi ninu awon oku; Ajinde ati Iye; Kiki oro kan to so ile aye ro; Apata Ayeraiye; Apata aidigbolu-eni digbolu a wo womu-womu; Eleti lu kara bi ajere; Ape-je, Aipe-je; Baba fun alaini baba; Oko opo; Eru jeje leti okun pupa; Ekun oko Farao; Oke-tiiri ti-ko-le-wo; Oko mi; Olorun mi; Olugbala mi: Olurapada mi; Afuni teni keni ko le gba; Agbani te nikeni ko le de; Agbeni teda aye kan ko le ja kule;Olowo gbogboro ti nyomo re ninu ofin aye; Ara-ti-nsan-nigbo-ti-tigbo-tiju-pa-lolo-lo; Olowo-ori-mi; Oba awon oba; Olorun awon olorun, Afobaje ti a ko le ro loye; Oba to nfi oba je; Oba to nse ohun gbogbo lodu lodu to nje Olodumare; Ogbenu-wundia sola; Ogbenu adalebo sewa; O gbe nu omo eniyan fohun; Alfa ati Omega; Ibeere ati opin; Eni ibeere ati opin; Saju aye loti wa, aye wa, Baba mi wa sibe, Olorun mi ti yio ma wa nigba ti aye ko ni si mo;Emi ni ninu emi ni; Emi ni mase beru; Akara iye; odo to nsan fun aanu ti kii gbe; Ajidara; Ajisewa; Aiku Aidibaje; Alagbala iyanu; Alagbala a-de'u're; Alagbala to ni kokoro to nsi to nti; Alade wura, Alade ogo; Alade ewa; Ewa to tinu ewa jade; olowo mimo; Oniwa mimo; Alade mimo; Mimo, mimo ninu ogo nla ti kii di baje, Oloruko egbaagbeje.

Y'all rock my world!!!! *kisses*

Share this post

Post a comment

:ambivalent:
:angry:
:confused:
:content:
:cool:
:crazy:
:cry:
:embarrassed:
:footinmouth:
:frown:
:gasp:
:grin:
:heart:
:hearteyes:
:innocent:
:kiss:
:laughing:
:minifrown:
:minismile:
:moneymouth:
:naughty:
:nerd:
:notamused:
:sarcastic:
:sealed:
:sick:
:slant:
:smile:
:thumbsdown:
:thumbsup:
:wink:
:yuck:
:yum:

Next Post
Newer Post
Previous Post
Older Post